Yoruba Reading

If you're trying to practice your Yoruba Reading then the page below should help. You will be able to sharpen your comprehension and understanding of the sample text below, which is part of the Article 26 and 27 from the Universal Declaration of Human Rights. The first section is in Yoruba and the second part is in English. Also don't forget to check the rest of our other lessons listed on Learn Yoruba. Enjoy the rest of the lesson!

Yoruba Reading

Read the following text very carefully and see what you can understand without looking at the English translation, and see what you understood from it.

Yoruba Reading
Abala ke̟rìndínló̟gbò̟n.
1) E̟nì kò̟ò̟kan ló ní è̟tó̟ láti kó̟ è̟kó̟. Ó kéré tán, è̟kó̟ gbo̟dò̟ jé̟ ò̟fé̟ ní àwo̟n ilé-è̟kó̟ alákò̟ó̟bè̟rè̟. E̟kó̟ ní ilé-è̟kó̟ alákò̟ó̟bè̟rè̟ yìí sì gbo̟dò̟ jé̟ dandan. A gbo̟dò̟ pèsè è̟kó̟ is̟é̟-o̟wó̟, àti ti ìmò̟-è̟ro̟ fún àwo̟n ènìyàn lápapò̟. Àn fàní tó dó̟gba ní ilé-è̟kó̟ gíga gbo̟dò̟ wà ní àró̟wó̟tó gbogbo e̟ni tó bá tó̟ sí.
2) Ohun tí yóò jé̟ ète è̟kó̟ ni láti mú ìlo̟síwájú tó péye bá è̟dá ènìyàn, kí ó sì túbò̟ rí i pé àwo̟n ènìyàn bò̟wò̟ fún è̟tó̟ o̟mo̟nìyàn àti àwo̟n òmìnira wo̟n, tó jé̟ kò-s̟eé-má-nìí. E tò è̟kó̟ gbo̟dò̟ lè rí i pé è̟mí; ìgbó̟ra-e̟ni-yé, ìbágbépò̟ àlàáfíà, àti ìfé̟ ò̟ré̟-sí-ò̟ré̟ wà láàrin orílè̟-èdè, láàrin è̟yà kan sí òmíràn àti láàrin e̟lé̟sìn kan sí òmíràn. E tò-è̟kó̟ sì gbo̟dò̟ kún àwo̟n akitiyan Àjo̟-ìsò̟kan orílè̟-èdè àgbáyé ló̟wó̟ láti rí i pé àlàáfíà fìdí múlè̟.
3)Àwo̟n òbí ló ní è̟tó̟ tó ga jù lo̟ láti yan è̟kó̟ tí wó̟n bá fé̟ fún àwo̟n o̟mo̟ wo̟n.
Abala ke̟tàdínló̟gbò̟n.
1) E̟nì kò̟ò̟kan ló ní è̟tó̟ láìjé̟ pé a fi ipá mú un láti kópa nínú àpapò̟ ìgbé ayé àwùjo̟ rè̟, kí ó je̟ ìgbádùn gbogbo ohun àmús̟e̟ wà ibè̟, kí ó sì kópa nínú ìdàgbàsókè ìmò̟ sáyé̟n sì àti àwo̟n àn fàní tó ń ti ibè̟ jáde.
2) E̟nì kò̟ò̟kan ló ní è̟tó̟ sí ààbò àn fàní ìmo̟yì àti ohun ìní tí ó je̟ yo̟ láti inú is̟é̟ yòówù tí ó bá s̟e ìbáà s̟e ìmò̟ sáyé̟n sì, ìwé kíko̟ tàbí is̟é̟ o̟nà.

Below is the translation of the above text, check what you understood without the help of the dictionary, after reading the translation one time, go back up and read the Yoruba text and see if you can recognize the more words this time.

English Translation
Article 26
1. Everyone has the right to education. Education shall be free, at least in the elementary and fundamental stages. Elementary education shall be compulsory. Technical and professional education shall be made generally available and higher education shall be equally accessible to all on the basis of merit.
2. Education shall be directed to the full development of the human personality and to the strengthening of respect for human rights and fundamental freedoms. It shall promote understanding, tolerance and friendship among all nations, racial or religious groups, and shall further the activities of the United Nations for the maintenance of peace.
3. Parents have a prior right to choose the kind of education that shall be given to their children.
Article 27
1. Everyone has the right freely to participate in the cultural life of the community, to enjoy the arts and to share in scientific advancement and its benefits.
2. Everyone has the right to the protection of the moral and material interests resulting from any scientific, literary or artistic production of which he is the author.

Reading and comprehension are very important in Yoruba. Once you're done with Yoruba Reading, you might want to check the rest of our Yoruba lessons here: Learn Yoruba. Don't forget to bookmark this page.

Menu:

Alphabet

Phrases

Adjectives

Yoruba Homepage

Numbers

Nouns

Vocabulary

Learn Yoruba

Plural

Videos

Practice

The links above are only a small sample of our lessons, please open the left side menu to see all links.

Copyright © 2019 MYLANGUAGES.ORG.